Ọ̀la, àwọn ènìyàn káàkiri àgbáyé yóò péjọ láti ṣe ayẹyẹ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run pẹ̀lú Ìpèníjà Bíbélì Ọjọ́ 30. Ìwọ náà sì lè kópa nínú rẹ̀!
Yálà kí àníyàn rẹ dínkù, kí ìdáwà rẹ dínkù, tàbí kí o ní ìgboyà sí i láti pín ìgbàgbọ́ rẹ, ìdúróṣinṣin nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ń yí ohun gbogbo padà—títí kan ìwọ náà.
Bẹ̀rẹ̀ ní Oṣù kọkànlá, máa lo Ohun Èlò Bíbélì rẹ fún ọgbọ̀n 30 ọjọ́ léraléra, kí o sì jèrè Àmì-ẹ̀yẹ àkànṣe Oṣù Bíbélì Àgbáyé.
Ìfìwéránṣẹ́ yí tún wà ní:


