Ọ̀la, àwọn ènìyàn káàkiri àgbáyé yóò darapọ̀ mọ́ ọ bí o ṣe ń kópa nínú Ìdánwò Bíbélì Ọjọ́ Ọgbọ̀n 30!
Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ní agbára láti yí ìgbésí ayé padà. Ní oṣù yìí, báwo ni yóò ṣe nípa lórí tìrẹ? Ẹ jẹ́ kí a fi ìdùnnú àti ìfojúsọ́nà hàn fún ohun tí Ọlọ́run yóò ṣe ní oṣù yìí.
Múra sílẹ̀ fún Oṣù Bíbélì Àgbáyé nípa fífi Ètò Ọjọ́ 30 pamọ́.
This post is also available in:


