Lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí, àwọn ènìyàn ní gbogbo àgbáyé ń ṣayẹyẹ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run pẹ̀lú Ìdíje Bíbélì Ọjọ́ 30. Kò sì tíì pẹ́ jù láti darapọ mọ rẹ!
D’ara pọ̀ mọ́ ìpèníjà náà
Yálà o nílò láti ní àlàáfíà sí i, ìrètí sí i, tàbí ìgboyà sí i, Ìduróṣinṣin nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run a máa yí ohun gbogbo padà.
Fojú inú wo ohun tí Ọlọ́run lè ṣe bí o bá pinnu láti máa ka Ọ̀rọ̀ Rẹ̀ lójoojúmọ́.
Lo Ohun èlò Bíbélì rẹ fún ọgbọ̀n ọjọ́ 30 ní tẹ̀léǹtẹ̀lé ní oṣù yìí láti gba Àmì Ẹ̀yẹ Oṣù Bíbélì Àgbáyé àkànṣe yìí.

Ìfìwéránṣẹ́ yí tún wà ní:

