Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ń yí ìgbésí ayé padà. Ó sì lè yí tìrẹ padà.

Ṣe Àjọyọ̀ Oṣù Bíbélì Àgbáyé

Ní oṣù Bélú yìí, àwọn ènìyàn kárí ayé ń kóra jọ láti ṣe àjọyọ̀ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ní àkókò Oṣù Bíbélì Àgbáyé. 

Darapọ̀ mọ́ ìgbìmọ̀ Bíbélì àgbáyé pẹ̀lú Ìdíje Bíbélì Ọlọ́gbọ̀n ọjọ́. 

D’ara pọ̀ mọ́ ìpèníjà náà

Yálà ó jẹ́ pé o fẹ́ kí ìdààmú ọkàn rẹ dínkù, kí ìdánìkanwà dínkù, tàbí kí o ní ìgboyà sí i nínú sísọ nípa ìgbàgbọ́ rẹ, àwọn ìwádìí fi hàn pé ìdúróṣinṣin nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ń yí ohun gbogbo padà. 

Báwo ni Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ṣe ń yí ọ padà?    

Bẹ̀rẹ̀ ní oṣù Bélú, ṣe àmúlò Ohun-èlò Bíbélì fún ọgbọ̀n ọjọ́ ní tẹ̀léǹtẹ̀lé, wàá ri Àmì Ẹ̀yẹ Oṣù Bíbélì Àgbáyé àkànṣe gbà.

Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ń yí ìgbésí ayé padà. Ó sì lè yí tìrẹ padà.

Share this post:

Ìfìwéránṣẹ́ yí tún wà ní: Gẹ̀ẹ́sì Èdè Afrikaans Èdè Indonesia Jamaní Èdè Sípénì Èdè Filipino (Tagalog) Faransé Èdè Ìtàló Èdè Dutch Èdè Pọtugí Èdè Romanian Èdè Rọ́síà Èdè Japaní Èdè China (Èyí tó rọrùn) Èdè China (ìbílẹ̀) Èdè Korea Èdè Lárúbáwá Èdè Belarusian Èdè Bengali Èdè Bulgaria Èdè Danish Èdè Finnish Gíríkì Hébérù Èdè Hindi Èdè Hungary Èdè Malay Èdè Mongolian Èdè Nepali Èdè Norwegian Pẹ́rúsì Èdè Polish Èdè Pọtugí (Potugal) Èdè Slovak Èdè Swahili Èdè Swedish Èdè Tamil Èdè Telugu Èdè Thai Èdè Turkish Èdè Ukarain Èdè Urdu Èdè Vietnamese Èdè Zulu Èdè Czech Èdè Khmer Èdè Malayali Èdè Sípénì (Spain) Èdè Burmese Èdè Lithuania Èdè Macedónìà Èdè Burmese (Zawgyi) Èdè Serbia Armenian Èdè Icelandic Èdè Croatia Èdè Albania Èdè Welsh Èdè Catalan Èdè Latvia Èdè Haitian Creole Shona Èdè Sorani Kurdish Èdè Xosa