Ní oṣù Bélú yìí, àwọn ènìyàn kárí ayé ń kóra jọ láti ṣe àjọyọ̀ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ní àkókò Oṣù Bíbélì Àgbáyé.
Darapọ̀ mọ́ ìgbìmọ̀ Bíbélì àgbáyé pẹ̀lú Ìdíje Bíbélì Ọlọ́gbọ̀n ọjọ́.
D’ara pọ̀ mọ́ ìpèníjà náà
Yálà ó jẹ́ pé o fẹ́ kí ìdààmú ọkàn rẹ dínkù, kí ìdánìkanwà dínkù, tàbí kí o ní ìgboyà sí i nínú sísọ nípa ìgbàgbọ́ rẹ, àwọn ìwádìí fi hàn pé ìdúróṣinṣin nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ń yí ohun gbogbo padà.
Báwo ni Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ṣe ń yí ọ padà?
Bẹ̀rẹ̀ ní oṣù Bélú, ṣe àmúlò Ohun-èlò Bíbélì fún ọgbọ̀n ọjọ́ ní tẹ̀léǹtẹ̀lé, wàá ri Àmì Ẹ̀yẹ Oṣù Bíbélì Àgbáyé àkànṣe gbà.


