
Times Square. Piccadilly Circus. Osaka.
Ní oṣù yìí, a ń ṣe ayẹyẹ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run lọ́nà tó dùn mọ́ni! Àwọn ibi díẹ̀ tí a ti ń ṣe ayẹyẹ Bíbélì lónìí rèé…



Ṣíṣe àfihàn Bíbélì ní àwọn ibi gbajúmọ̀ wọ̀nyí jẹ́ àǹfààní ńlá láti gba àwọn ènìyàn níyànjú láti padà sí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run tàbí láti kẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ fún ìgbà àkọ́kọ́.
Ayẹyẹ yìí ń wáyé káàkiri àgbáyé, ìwọ náà sì lè wà lára rẹ̀.
Ní gbogbo ìgbà tí o bá ṣí Bíbélì, o ń jẹ́ kí òtítọ́ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run yí ọ padà.
Ìfìwéránṣẹ́ yí tún wà ní:
