Àwọn ọmọdé ń nífẹ̀ẹ́ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run…

Àwọn ọmọdé ń nífẹ̀ẹ́ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run…

Ní ìgbà tí Jóṣúà lọ sí ìsìn Bíbélì kan fún àwọn ọmọdé, ó ṣàwárí Ohun-èlò Bíbélì fún Àwọn Ọmọdé. Ìgbà náà ni ohun gbogbo yí padà.

A bí í ní afọ́jú, ó kọ́ pé òun kàn lè fetí sí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run, kò sì pẹ́ tí ó fi nífẹ̀ẹ́ sí Bíbélì.

Ní ìgbà tí bàbá rẹ̀ rí ayọ̀ ìyípadà tí ó wà nínú ọmọ rẹ̀, ó lọ sí ṣọ́ọ̀ṣì, ó sì fi ayé rẹ̀ fún Krístì ní ọjọ́ náà gan-an. Láìpẹ́ lẹ́yìn náà, gbogbo ìdílé wọn gba Jésù.

Ní báyìí, Jóṣúà àti àwọn òbí rẹ̀ ń sìn nínú ṣọ́ọ̀ṣì agbègbè wọn, wọ́n ń ka Bíbélì papọ̀ lójoojúmọ́, wọ́n sì nífẹ̀ẹ́ láti pín Ohun-èlò Bíbélì fún Àwọn Ọmọdé fún àwọn ẹlòmíràn.

Ṣé o fẹ́ kí àwọn ọmọdé tí ó wà ní àyíká rẹ nífẹ̀ẹ́ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run? Fún Oṣù Bíbélì Àgbáyé, wo Ohun-èlò Bíbélì fún Àwọn Ọmọdé, kí o sì fi Ìwé Mímọ́ hàn àwọn ọmọdé nípasẹ̀ àwọn ìtàn Bíbélì tí wọ́n lè kópa nínú rẹ̀. ⬇️

Ṣí Ohun èlò Bíbélì fún Àwọn Ọmọdé

Share this post:

Ìfìwéránṣẹ́ yí tún wà ní: Gẹ̀ẹ́sì Èdè Indonesia Jamaní Èdè Sípénì Èdè Filipino (Tagalog) Faransé Èdè Ìtàló Èdè Dutch Èdè Pọtugí Èdè Romanian Èdè Rọ́síà Èdè Japaní Èdè China (Èyí tó rọrùn) Èdè China (ìbílẹ̀) Èdè Korea Èdè Lárúbáwá Èdè Belarusian Èdè Bengali Èdè Bulgaria Èdè Danish Èdè Finnish Gíríkì Hébérù Èdè Hindi Èdè Hungary Èdè Malay Èdè Mongolian Èdè Nepali Èdè Norwegian Pẹ́rúsì Èdè Polish Èdè Pọtugí (Potugal) Èdè Slovak Èdè Swahili Èdè Swedish Èdè Tamil Èdè Telugu Èdè Thai Èdè Turkish Èdè Ukarain Èdè Urdu Èdè Vietnamese Èdè Zulu Èdè Czech Èdè Khmer Èdè Malayali Èdè Sípénì (Spain) Èdè Burmese Èdè Lithuania Èdè Macedónìà Èdè Serbia Armenian Èdè Icelandic Èdè Croatia Èdè Welsh Èdè Catalan Èdè Latvia Èdè Haitian Creole Shona Èdè Sorani Kurdish Èdè Xosa