O pinnu láti ka Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run fún for 30 days … o ò sì dá ṣe é.
O darapọ̀ mọ́ àwọn ènìyàn Ẹgbẹ̀rún mẹ́ta tó lé ní tí wọ́n ń bá Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run lò ní oṣù kọkànlá.
Ọ̀kan nínú àwọn ènìyàn tí o dara pọ̀ mọ́ ni Pamela.
Nígbà tí Pamela ń dàgbà, ó ní ìrora púpọ̀, ọgbẹ́ ọkàn, àti ọ̀pọ̀ ìbéèrè nípa ẹni tí ó jẹ́. Ìgbà yẹn ni ó yíjú sí Bíbélì tí ó sì rí Ètò kan nípa ìdánimọ̀.
“Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run fi hàn mí pé Jésù ti fún mi ní ìdánimọ̀ mi. Ṣùgbọ́n èmi ni mi ò tíì ṣàwárí rẹ̀. Òtítọ́ yìí ló yí ohun gbogbo padà.”
Pamela, MEXICO
Oṣù Bíbélì Àgbáyé lè máa parí, ṣùgbọ́n Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run kì í ṣe fún àkókò kan ṣoṣo. Ó yẹ kó jẹ́ apá kan nínu ìgbésí ayé ojoojúmọ́ rẹ, bí o ṣe ń jẹ́ kí Òtítọ́ yí ọ padà, bí ó ṣe yí ìgbésí ayé Pamela padà.
Nítorí náà, máa tẹ̀síwájú! Tẹ̀síwájú láti máa ní ìbáṣepọ̀ pẹ́lú Ọlọ́run nípasẹ̀ Ọ̀rọ̀ Rẹ̀, kí o sì wo ohun tí yóò ṣe…
Ìfìwéránṣẹ́ yí tún wà ní:

