Oṣù Bíbélì Àgbáyé ti fẹ́rẹ̀ẹ́ dé!

Email-Header-starts-tomorrow

Ṣe Àjọyọ̀ Oṣù Bíbélì Àgbáyé

Ọ̀la, àwọn ènìyàn káàkiri àgbáyé yóò péjọ láti ṣe ayẹyẹ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run pẹ̀lú Ìpèníjà Bíbélì Ọjọ́ 30. Ìwọ náà sì lè kópa nínú rẹ̀!

Má ṣe Pàdánù Ìpèníjà Náà

Yálà kí àníyàn rẹ dínkù, kí ìdáwà rẹ dínkù, tàbí kí o ní ìgboyà sí i láti pín ìgbàgbọ́ rẹ, ìdúróṣinṣin nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ń yí ohun gbogbo padà—títí kan ìwọ náà.

Bẹ̀rẹ̀ ní Oṣù kọkànlá, máa lo Ohun Èlò Bíbélì rẹ fún ọgbọ̀n 30 ọjọ́ léraléra, kí o sì jèrè Àmì-ẹ̀yẹ àkànṣe Oṣù Bíbélì Àgbáyé.

Share this post:

Oṣù Bíbélì Àgbáyé ti bẹ̀rẹ̀ báyìí, o sì ṣì lè dara pọ̀!

Oṣù Bíbélì Àgbáyé bẹ̀rẹ̀ nísinsin yìí!

Ṣe Àjọyọ̀ Oṣù Bíbélì Àgbáyé

Lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí, àwọn ènìyàn ní gbogbo àgbáyé ń ṣayẹyẹ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run pẹ̀lú Ìdíje Bíbélì Ọjọ́ 30. Kò sì tíì pẹ́ jù láti darapọ mọ rẹ!

D’ara pọ̀ mọ́ ìpèníjà náà

Yálà o nílò láti ní àlàáfíà sí i, ìrètí sí i, tàbí ìgboyà sí i, Ìduróṣinṣin nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run a máa yí ohun gbogbo padà.

Fojú inú wo ohun tí Ọlọ́run lè ṣe bí o bá pinnu láti máa ka Ọ̀rọ̀ Rẹ̀ lójoojúmọ́.

Lo Ohun èlò Bíbélì rẹ fún ọgbọ̀n ọjọ́ 30 ní tẹ̀léǹtẹ̀lé ní oṣù yìí láti gba Àmì Ẹ̀yẹ Oṣù Bíbélì Àgbáyé àkànṣe yìí.

Oṣù Bíbélì Àgbáyé ti bẹ̀rẹ̀ báyìí, o sì ṣì lè dara pọ̀!

Share this post:

Oṣù Bíbélì Àgbáyé bẹ̀rẹ̀ nísinsin yìí!

Oṣù Bíbélì Àgbáyé bẹ̀rẹ̀ nísinsin yìí!

Ṣe Àjọyọ̀ Oṣù Bíbélì Àgbáyé

Òní ni ìbẹ̀rẹ̀ Oṣù Bíbélì Àgbáyé! Fún ọgbọ̀n (30) ọjọ́ tó ń bọ̀, àwọn ènìyàn kárí ayé yóò kóra jọ láti lo àkókò nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run.

Ṣé o fẹ́ mọ ibi tí o ti lè bẹ̀rẹ̀? Wo àwọn Ètò wọ̀nyí láti bẹ̀rẹ̀ ìlọsíwájú Oṣù Bíbélì Àgbáyé rẹ!

Ṣàwárí Àwọn Ètò Mìíràn

Share this post:

Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ń yí ìgbésí ayé padà. Ó sì lè yí tìrẹ padà.

Ṣe Àjọyọ̀ Oṣù Bíbélì Àgbáyé

Ní oṣù Bélú yìí, àwọn ènìyàn kárí ayé ń kóra jọ láti ṣe àjọyọ̀ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ní àkókò Oṣù Bíbélì Àgbáyé. 

Darapọ̀ mọ́ ìgbìmọ̀ Bíbélì àgbáyé pẹ̀lú Ìdíje Bíbélì Ọlọ́gbọ̀n ọjọ́. 

D’ara pọ̀ mọ́ ìpèníjà náà

Yálà ó jẹ́ pé o fẹ́ kí ìdààmú ọkàn rẹ dínkù, kí ìdánìkanwà dínkù, tàbí kí o ní ìgboyà sí i nínú sísọ nípa ìgbàgbọ́ rẹ, àwọn ìwádìí fi hàn pé ìdúróṣinṣin nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ń yí ohun gbogbo padà. 

Báwo ni Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ṣe ń yí ọ padà?    

Bẹ̀rẹ̀ ní oṣù Bélú, ṣe àmúlò Ohun-èlò Bíbélì fún ọgbọ̀n ọjọ́ ní tẹ̀léǹtẹ̀lé, wàá ri Àmì Ẹ̀yẹ Oṣù Bíbélì Àgbáyé àkànṣe gbà.

Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ń yí ìgbésí ayé padà. Ó sì lè yí tìrẹ padà.

Share this post:

Gba Bíbélì ọ̀fẹ́ ti orí ayélujára

Gba Bíbélì ọ̀fẹ́

ti orí ayélujára fún fóònù àti tábúlẹ̀tì


Kà Bíbélì

Máa mú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run dání níbikíbi tó o bá lọ nípa ṣíṣàtìlẹyìn Bíbélì App lọ́fẹ̀ẹ́. Tẹ́tí sí ohùn Bíbélì, ṣe Àdúrà, kẹ́kọ̀ọ́ pẹ̀lú Àwọn Ọ̀rẹ́, àti púpọ̀ sí i fún ọ̀fẹ́.

Kà Bíbélì


Helpful links:
Kà Bíbélì lórí ayélujára – Yoruba

Share this post: